Jakọbu 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni ninu yín bá wà ninu ìyọnu, kí olúwarẹ̀ gbadura. Bí inú ẹnikẹ́ni ninu yín bá dùn, kí olúwarẹ̀ máa kọ orin ìyìn.

Jakọbu 5

Jakọbu 5:4-19