Jakọbu 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ fi ara yín sábẹ́ àṣẹ Ọlọrun. Ẹ dojú ìjà kọ Èṣù, yóo sì sálọ kúrò lọ́dọ̀ yín.

Jakọbu 4

Jakọbu 4:2-14