Jakọbu 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò mọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ si yín lọ́la. Nítorí ìkùukùu ni yín, tí ó wà fún àkókò díẹ̀, lẹ́yìn náà tí kò ní sí mọ́.

Jakọbu 4

Jakọbu 4:6-17