Jakọbu 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbo ni ogun ti ń wá? Níbo ni ìjà sì ti ń wá sáàrin yín? Ṣebí nípa ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ yín tí ó ń jagun ninu àwọn ẹ̀yà ara yín ni.

Jakọbu 4

Jakọbu 4:1-6