Jakọbu 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahọ́n ni a fi ń yin Oluwa ati Baba. Òun kan náà ni a fi ń ṣépè fún eniyan tí a dá ní àwòrán Ọlọrun.

Jakọbu 3

Jakọbu 3:4-13