Jakọbu 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹ̀dá pátá: ati ẹranko ni, ati ẹyẹ, ati àwọn ohun tí ń fàyà fà, ati àwọn ẹran omi, gbogbo wọn ni eniyan lè so lójú rọ̀.

Jakọbu 3

Jakọbu 3:3-11