Jakọbu 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹ̀ ń kẹ́gàn mẹ̀kúnnù. Ṣebí àwọn ọlọ́rọ̀ níí máa fìtínà yín, tí wọn máa ń fà yín lọ sí kóòtù!

Jakọbu 2

Jakọbu 2:5-15