Jakọbu 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ ẹ kò fi bẹ́ẹ̀ dá ìyapa sílẹ̀ láàrin ara yín, ǹjẹ́ ẹ kò sì máa ṣe ìdájọ́ pẹlu èrò burúkú.

Jakọbu 2

Jakọbu 2:1-6