Jakọbu 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí bákan náà ni Rahabu aṣẹ́wó gba ìdáláre nípa iṣẹ́, nígbà tí ó ṣe àwọn amí ní àlejò, tí ó jẹ́ kí wọ́n bá ọ̀nà mìíràn pada lọ?

Jakọbu 2

Jakọbu 2:17-26