Jakọbu 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa sọ̀rọ̀, kí ẹ sì máa hùwà gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó wà lábẹ́ ìdájọ́ òfin tí ó ń sọ eniyan di òmìnira.

Jakọbu 2

Jakọbu 2:9-17