Jakọbu 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹni tí ó bá pa gbogbo òfin mọ́, ṣugbọn tí ó rú ẹyọ kan ṣoṣo, ó jẹ̀bi gbogbo òfin.

Jakọbu 2

Jakọbu 2:1-14