Jakọbu 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará mi, níwọ̀n ìgbà tí ẹ ní igbagbọ ninu Oluwa wa, Jesu Kristi, Oluwa tí ó lógo, ẹ má máa ṣe ojuṣaaju.

Jakọbu 2

Jakọbu 2:1-10