Jakọbu 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ níláti ní ìfaradà títí dé òpin, kí ẹ lè di pípé, kí ẹ sì ní ohun gbogbo lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́, láìsí ìkùnà kankan.

Jakọbu 1

Jakọbu 1:1-12