Jakọbu 1:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí bí eniyan bá gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, tí kò fi ṣe ìwà hù, olúwarẹ̀ dàbí ẹni tí ó wo ojú ara rẹ̀ ninu dígí.

Jakọbu 1

Jakọbu 1:16-27