Jakọbu 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ bá lóyún, á bí ẹ̀ṣẹ̀; nígbà tí ẹ̀ṣẹ̀ bá gbilẹ̀ tán á bí ikú.

Jakọbu 1

Jakọbu 1:6-17