Jakọbu 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá fi ara da ìdánwò kú oríire, nítorí nígbà tí ó bá yege tán, yóo gba adé ìyè tí Ọlọrun ṣe ìlérí fún àwọn tí ó fẹ́ràn rẹ̀.

Jakọbu 1

Jakọbu 1:9-21