Ìwé Òwe 8:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. ó ń kígbe lóhùn rara lẹ́nu ibodè àtiwọ ìlú,ó ń ké ní ẹnu ọ̀nà àbáwọlé pẹlu,ó ń wí pé:

4. “Ẹ̀yin eniyan ni mò ń pè,gbogbo ọmọ eniyan ni mò ń ké sí.

5. Ẹ̀yin òpè, ẹ kọ́ ọgbọ́n,ẹ̀yin òmùgọ̀, ẹ fetí sí òye.

Ìwé Òwe 8