Ìwé Òwe 6:33-35 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Ọgbẹ́ ati àbùkù ni yóo gbà,ìtìjú rẹ̀ kò sì ní kúrò lára rẹ̀ laelae.

34. Nítorí owú jíjẹ a máa mú kí inú ọkọ ru,kò sì ní jẹ́ ṣàánú àlè bó bá di pé à ń gbẹ̀san.

35. Kò ní gba owó ìtanràn,ọpọlọpọ ẹ̀bùn kò sì ní lè tù ú lójú.

Ìwé Òwe 6