Ìwé Òwe 4:24-27 BIBELI MIMỌ (BM)

24. Má lọ́wọ́ ninu ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ,sì jìnnà sí ọ̀rọ̀ àgàbàgebè.

25. Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán,kí o sì kọjú sí ibi tí ò ń lọ tààrà.

26. Kíyèsí ìrìn ẹsẹ̀ rẹ,gbogbo ọ̀nà rẹ yóo sì là.

27. Má ṣe yà sí ọ̀tún tabi sí òsì,yipada kúrò ninu ibi.

Ìwé Òwe 4