Ìwé Òwe 31:29-31 BIBELI MIMỌ (BM)

29. “Ọpọlọpọ obinrin ni wọ́n ti ṣe ribiribi,ṣugbọn ìwọ ta gbogbo wọn yọ.”

30. Ẹ̀tàn ni ojú dáradára, asán sì ni ẹwà,obinrin tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni ó yẹ kí á yìn.

31. Fún un ninu èrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀,jẹ́ kí wọn máa yìn ín lẹ́nu ibodè nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

Ìwé Òwe 31