Ìwé Òwe 3:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọmọ mi, má ṣe gbàgbé ẹ̀kọ́ tí mo kọ́ ọ,sì pa òfin mi mọ́ lọ́kàn rẹ,

2. nítorí wọn óo fún ọ ní ẹ̀mí gígùnati ọpọlọpọ alaafia.

Ìwé Òwe 3