Ìwé Òwe 29:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí olódodo bá di eniyan pataki,àwọn eniyan a máa yọ̀,ṣugbọn nígbà tí eniyan burúkú bá wà lórí oyè,àwọn eniyan a máa kérora.

Ìwé Òwe 29

Ìwé Òwe 29:1-8