Ìwé Òwe 29:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí eniyan burúkú bá wà lórí oyè, ẹ̀ṣẹ̀ a máa pọ̀ síi,ṣugbọn lójú olódodo ni wọn yóo ti ṣubú.

Ìwé Òwe 29

Ìwé Òwe 29:9-20