Ìwé Òwe 29:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn apànìyàn kórìíra olóòótọ́ inú,wọ́n sì ń wá ọ̀nà láti pa á.

Ìwé Òwe 29

Ìwé Òwe 29:1-13