Ìwé Òwe 23:33-34 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Ojú rẹ yóo rí nǹkan àjèjì,ọkàn rẹ á máa ro èròkerò.

34. O óo dàbí ẹni tí ó dùbúlẹ̀ lórí agbami òkun,bí ẹni tí ó sùn lórí òpó ọkọ̀.

Ìwé Òwe 23