Ìwé Òwe 23:2-4 BIBELI MIMỌ (BM)

2. Tí o bá jẹ́ wọ̀bìà eniyan, ṣọ́ra,kí o má fi ọ̀bẹ lé ara rẹ lọ́fun.

3. Má jẹ́ kí oúnjẹ aládìídùn rẹ̀ wọ̀ ọ́ lójú,nítorí ó lè jẹ́ oúnjẹ ẹ̀tàn.

4. Má ṣe làálàá àṣejù láti kó ọrọ̀ jọ,fi ọgbọ́n sẹ́ ara rẹ.

Ìwé Òwe 23