Ìwé Òwe 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Má ṣe ìlara àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,ṣugbọn máa bẹ̀rù OLUWA lọ́jọ́ gbogbo.

Ìwé Òwe 23

Ìwé Òwe 23:16-26