Ìwé Òwe 23:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà tí o bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun,kíyèsí ẹni tí ó bá wà níwájú rẹ dáradára.

2. Tí o bá jẹ́ wọ̀bìà eniyan, ṣọ́ra,kí o má fi ọ̀bẹ lé ara rẹ lọ́fun.

3. Má jẹ́ kí oúnjẹ aládìídùn rẹ̀ wọ̀ ọ́ lójú,nítorí ó lè jẹ́ oúnjẹ ẹ̀tàn.

Ìwé Òwe 23