Ìwé Òwe 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwà ipá àwọn ẹni ibi ni yóo gbá wọn dànù,nítorí pé wọ́n kọ̀ láti ṣe òtítọ́.

Ìwé Òwe 21

Ìwé Òwe 21:1-10