Ìwé Òwe 2:6-8 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Nítorí OLUWA níí fún ni ní ọgbọ́n,ẹnu rẹ̀ sì ni òye ati ìmọ̀ ti ń wá.

7. Ó fún àwọn tí wọn dúró ṣinṣin ní ìjìnlẹ̀ ọgbọ́n,òun ni ààbò fún àwọn tí wọ́n ń rin ọ̀nà ẹ̀tọ́.

8. Ó ń tọ́ wọn sí ìdájọ́ òtítọ́,ó sì ń pa ọ̀nà àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀ mọ́.

Ìwé Òwe 2