Ìwé Òwe 19:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn arakunrin talaka ni wọ́n kórìíra rẹ̀,kí á má ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ ti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jìnnà sí i!Ó fọ̀rọ̀ ẹnu fà wọ́n títí, sibẹ wọn kò súnmọ́ ọn.

Ìwé Òwe 19

Ìwé Òwe 19:6-9