Ìwé Òwe 17:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹrú tí ó bá mọ ìwà hù, yóo di ọ̀gá lórí ọmọ tí ń hùwà ìbàjẹ́,yóo sì jókòó pín ninu ogún bí ẹni pé ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ni.

Ìwé Òwe 17

Ìwé Òwe 17:1-3