Ìwé Òwe 16:14-16 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Iranṣẹ ikú ni ibinu ọba,ọlọ́gbọ́n eniyan níí tù ú lójú.

15. Ìyè wà ninu ojurere ọba,ojurere rẹ̀ sì dàbí ṣíṣú òjò ní àkókò òjò àkọ́rọ̀.

16. Ó sàn kí eniyan ní òye ju kí ó ní wúrà lọ,ó sì sàn kí eniyan yan ìmọ̀ ju kí ó yan fadaka lọ.

Ìwé Òwe 16