Ìwé Òwe 16:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Èrò ọkàn ni ti eniyanṣugbọn OLUWA ló ni ìdáhùn.

2. Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó mọ́ lójú ara rẹ̀,ṣugbọn OLUWA ló rí ọkàn.

3. Fi gbogbo àdáwọ́lé rẹ lé OLUWA lọ́wọ́,èrò ọkàn rẹ yóo sì yọrí sí rere.

Ìwé Òwe 16