Ìwé Òwe 15:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ń ṣojúkòkòrò èrè àìtọ́ ń kó ìyọnu bá ilé wọn,ṣugbọn àwọn tí wọn kórìíra àbẹ̀tẹ́lẹ̀ yóo yè.

Ìwé Òwe 15

Ìwé Òwe 15:18-28