Ìwé Òwe 14:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọn ń pète ibi ti ṣìnà,ṣugbọn àwọn tí wọn ń gbèrò ire yóo rí ojurere ati òtítọ́.

Ìwé Òwe 14

Ìwé Òwe 14:18-29