Ìwé Òwe 14:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọ́gbọ́n obinrin a máa kọ́ ilé rẹ̀,ṣugbọn òmùgọ̀ a máa fi ọwọ́ ara rẹ̀ tú tirẹ̀ palẹ̀.

2. Ẹni tí ń rìn pẹlu òótọ́ inú yóo bẹ̀rù OLUWA,ṣugbọn ẹni tí ń rin ìrìn ségesège yóo kẹ́gàn rẹ̀.

Ìwé Òwe 14