Ìwé Òwe 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ àwọn eniyan burúkú dàbí ẹni tí ó lúgọ láti pa eniyan,ṣugbọn ọ̀rọ̀ ẹnu olódodo a máa gbani là.

Ìwé Òwe 12

Ìwé Òwe 12:4-13