Ìwé Òwe 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Òtítọ́ inú àwọn olódodo a máa tọ́ wọn,ṣugbọn ìwà aiṣootọ àwọn ọ̀dàlẹ̀ níí pa wọ́n.

Ìwé Òwe 11

Ìwé Òwe 11:1-8