Ìwé Òwe 1:13-16 BIBELI MIMỌ (BM)

13. a óo rí àwọn nǹkan olówó iyebíye kó,ilé wa yóo sì kún fún ìkógun.

14. Ìwọ ṣá darapọ̀ mọ́ wa,kí á sì jọ lẹ̀dí àpò pọ̀.”

15. Ọmọ mi, má bá wọn kẹ́gbẹ́,má sì bá wọn rìn,

16. nítorí ọ̀nà ibi ni ẹsẹ̀ wọn máa ń yá sí,wọ́n a sì máa yára láti paniyan.

Ìwé Òwe 1