Ìwé Òwe 1:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn òwe tí Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli pa,

2. kí àwọn eniyan lè ní ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́,kí òye ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lè yé wọn,

3. láti gba ẹ̀kọ́, tí yóo kọ́ni lọ́gbọ́n,òdodo, ẹ̀tọ́ ati àìṣojúṣàájú,

Ìwé Òwe 1