Ìwé Oníwàásù 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí alààyè mọ̀ pé òun óo kú, ṣugbọn òkú kò mọ nǹkankan mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní èrè kan mọ́, a kò sì ní ranti wọn mọ́.

Ìwé Oníwàásù 9

Ìwé Oníwàásù 9:3-6