Ìwé Oníwàásù 9:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin ọlọ́gbọ́n kan wà níbẹ̀ tí ó jẹ́ talaka, ó gba ìlú náà sílẹ̀ pẹlu ọgbọ́n rẹ̀, ṣugbọn ẹnìkan kò ranti talaka náà mọ́.

Ìwé Oníwàásù 9

Ìwé Oníwàásù 9:8-17