Ìwé Oníwàásù 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rí àwọn ẹni ibi tí a sin sí ibojì. Nígbà ayé wọn, wọn a ti máa ṣe wọlé-wọ̀de ní ibi mímọ́, àwọn eniyan a sì máa yìn wọ́n, ní ìlú tí wọn tí ń ṣe ibi. Asán ni èyí pẹlu.

Ìwé Oníwàásù 8

Ìwé Oníwàásù 8:2-17