Ìwé Oníwàásù 7:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀kọ́ tí mo rí kọ́ ni pé rere ni Ọlọrun dá eniyan, ṣugbọn àwọn ni wọ́n wá oríṣìíríṣìí ọ̀nà àrékérekè fún ara wọn.

Ìwé Oníwàásù 7

Ìwé Oníwàásù 7:21-29