Ìwé Oníwàásù 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan wọnyi ni mo ti fi ọgbọ́n wádìí. Mo sọ ninu ara mi pé, “Mo fẹ́ gbọ́n,” ṣugbọn ọgbọ́n jìnnà sí mi.

Ìwé Oníwàásù 7

Ìwé Oníwàásù 7:17-26