Ìwé Oníwàásù 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu gbogbo ìgbé-ayé asán mi, mo ti rí àwọn nǹkan wọnyi: Mo ti rí olódodo tí ó ṣègbé ninu òdodo rẹ̀, mo sì ti rí eniyan burúkú tí ẹ̀mí rẹ̀ gùn, pẹlu bí ó ti ń ṣe ibi.

Ìwé Oníwàásù 7

Ìwé Oníwàásù 7:7-21