Ìwé Oníwàásù 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò rí oòrùn rí, kò sì mọ nǹkankan, sibẹsibẹ ó ní ìsinmi; nítorí náà ó sàn ju ẹni tí ó bí ọgọrun-un ọmọ tí ó kú láìrí ẹni sin òkú rẹ̀ lọ.

Ìwé Oníwàásù 6

Ìwé Oníwàásù 6:1-8