Ìwé Oníwàásù 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan tí ó jọba lé lórí pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí wọn kò ní òǹkà; sibẹ, àwọn ìran tí ó bá dé lẹ́yìn kò ní máa yọ̀ nítorí rẹ̀. Dájúdájú asán ati ìmúlẹ̀mófo ni èyí.

Ìwé Oníwàásù 4

Ìwé Oníwàásù 4:15-16