Ìwé Oníwàásù 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wí ní ọkàn ara mi pé Ọlọrun ń dán àwọn ọmọ eniyan wò, láti fihàn wọ́n pé wọn kò yàtọ̀ sí ẹranko;

Ìwé Oníwàásù 3

Ìwé Oníwàásù 3:16-22